Dataset Viewer
Auto-converted to Parquet
unique_id
int64
1.2k
2.4k
text
stringlengths
12
131
speaker_id
stringdate
1234-01-01 00:00:00
1234-01-01 00:00:00
audio
audioduration (s)
2.06
9.83
__index_level_0__
int64
1.2k
2.4k
1,204
Mo ní kí o fín ilé rẹ lánàá.
1234
1,203
1,205
Jíjẹ owú láàrin àwon ọmọ je oun ti a gbúdọ̀ gbe yẹ̀wo ni ojo iwáju
1234
1,204
1,206
Igi ọ̀gẹ̀dẹ̀ àgbagbà ati ọ̀gẹ̀dẹ̀ lásán jọra.
1234
1,205
1,207
A ma lọ ra awon ohun èlò ìsìnkú
1234
1,206
1,208
Ìlú Ìlọrin lè padà sí apá Ilẹ̀ Yorùbá tí wọ́n bá dá orílẹ̀-èdè Yorùbá sílẹ̀
1234
1,207
1,209
Ẹ máa kọ́ orin tuntun lálẹ́ yìí.
1234
1,208
1,210
Wà á lọ pàrọ̀ báńkì re sí òmíràn.
1234
1,209
1,211
Inú bàbá mi ò ní dùn ti n bá wọ òrùka ìka esè.
1234
1,210
1,212
Àwọn Mùsùlùmí máa ń jọ́sìn nínú Mọ́ṣáláṣí.
1234
1,211
1,213
Ìgbéyàwó ònílé ìjọsìn ni mo fẹ́
1234
1,212
1,214
Àwọ adiye ilé yìí má ń yé ẹyin
1234
1,213
1,215
Láti ìgbà wo ni Olorì ti dé?
1234
1,214
1,216
Ọjọ́ Àìkú jẹ́ ọjọ́ ìjọsìn fún àwọn Kírísítẹ́nì
1234
1,215
1,217
Ṣíbí ni a fi ń jeun
1234
1,216
1,218
Ìyá agba lo wo ọmọ naa dàgba.
1234
1,217
1,219
Àwọ̀n ẹ̀fọn náà fa ìtànkálẹ̀ àìsàn ibà.
1234
1,218
1,220
Awọn ile iwosan n pese itọju ilera pataki fun awọn agbalagba.
1234
1,219
1,221
Onírúurú nǹkan ni igi wà fún.
1234
1,220
1,222
Òlá lòjò isinkú óbirin yèn
1234
1,221
1,223
Ijọba yoo wa ojutu si iṣoro ailaabo
1234
1,222
1,224
Èrọ Abẹ̀bẹ̀ oníná náà dáwọ́ iṣẹ́ dúró ní àárọ̀ yí.
1234
1,223
1,225
Dókítà sọ pé àìsàn ọkàn ni ó ṣe ikú pa Femi.
1234
1,224
1,226
Bàtà aláwò ni, ó le.
1234
1,225
1,227
Ìlù gbẹ̀dú tí wọ́pọ̀ láàrin àwọn Bìnì
1234
1,226
1,228
Ewé kaṣú ni a fẹ́ fi ṣe agbo ibà
1234
1,227
1,229
Ri daju pe o se itoju ara re daradara
1234
1,228
1,230
sola je atuko oju omi
1234
1,229
1,231
ṣé wọn yóò bẹ̀rẹ̀ ìjà náà lọ́sẹ̀ tó ń bọ̀
1234
1,230
1,232
Ọlú súkù yẹ kó gbà ẹgbẹrún àkẹkọ
1234
1,231
1,233
Ìgbà wo ni Ìmáàmù náà yóò pe ìrun?
1234
1,232
1,234
Kò ní sí àwọn wòlíì níbi ìgbeyàwó kóòtù
1234
1,233
1,235
Mo ṣábẹwò sí ile awon omo orúkàn ni ọṣù tó kọja..
1234
1,234
1,236
Ilé aláìní bábá wà fún awọn ọmọde tí bábá wọn tí kú.
1234
1,235
1,237
Amunututu má ń fún ènìyàn ní ẹ̀jẹ̀
1234
1,236
1,238
Ọ̀pọ̀ ènìyàn máa ń ránṣọ pẹ̀lú aṣọ ankara.
1234
1,237
1,239
opo oro la n so fomoluabi to ba denu re a dodindi
1234
1,238
1,240
Tani ó gbá yàrá àwọn olùkọ́?
1234
1,239
1,241
Ìnàkí jẹ́ ẹranko tó fi ìwà jọ ènìyàn.
1234
1,240
1,242
Mo sọ pe Emi yoo ra rite gala ni ọjọ aje
1234
1,241
1,243
Bẹ̀ẹ̀ni, mo fẹ dé pápá ọkò òfurufú.
1234
1,242
1,244
kíniun loba eranko ninu igbo
1234
1,243
1,245
Ó wọ́ ìlẹ̀kẹ̀ ìdí
1234
1,244
1,246
Awọn ọmọ ilé-ìwé yóò lọ sí ibi-iṣere lakoko ìsinmi
1234
1,245
1,247
Ilé ẹjọ́ á gba omi lẹgbẹ èrò lónìí
1234
1,246
1,248
Bẹ́ẹ̀ni, Mo mọ bí a tin ńṣe ìrẹ́sì díndi
1234
1,247
1,249
Nepa ti ge asopọ ina wa
1234
1,248
1,250
Obìnrin náà yan ẹran náà fẹ́rẹ́fẹ́
1234
1,249
1,251
Làmọ́lẹ̀ jẹ ọkan lára àwọn sítai irun sise nilẹ Yorùbá
1234
1,250
1,252
Àpẹẹrẹ ẹranko ìgbẹ́ ni àmọ̀tẹ́kùn.
1234
1,251
1,253
Ìpele oyún mẹ́ta ni ó wà.
1234
1,252
1,254
Onídìrí mi mọṣẹ́ rẹ̀ dájú.
1234
1,253
1,255
Ènìyàn kò lè wà láì ba ẹlòmíràn sọ̀rọ̀.
1234
1,254
1,256
Sítẹ́rìnì ọkọ̀ náà ṣòro láti wà.
1234
1,255
1,257
Gbe omo wa ki mi, owo ni lan ni
1234
1,256
1,258
Wásáápu mi yoo kọja akoko rẹ ni ọjọ mẹta to nbọ
1234
1,257
1,259
Okùnrin naa fi ipá bá ọmọ ọmọ rẹ̀ sùn
1234
1,258
1,260
Ṣé ó máa jáde pẹ̀lú ìdílé rẹ̀ ní ọ̀la?
1234
1,259
1,261
Ṣé o lè gba Bólú gbọ́?
1234
1,260
1,262
Nigbawo ni iwọ yoo fun mi ni bureedi?
1234
1,261
1,263
Iyọ jẹ̀ nkan ọ̀bẹ̀ tí o wọpọ̀ julọ ti a n lo ní gbogbo ọ̀unjẹ̀ tí a n ṣẹ.
1234
1,262
1,264
Tí o ba di ọjọ́ iwájú, pátákó funfun ni gbogbo ilé ẹ̀kọ́ o ma lò
1234
1,263
1,265
Oogun aloju ko dara.
1234
1,264
1,266
Àpo owó ẹyọ kàn ní iye lórí púpọ̀ nígbà náà.
1234
1,265
1,267
Àwọn ará ilé-ìwòsàn ní kí wọ́n kó ẹrù ọmọ wa sí osipitu.
1234
1,266
1,268
Ọmọ náà wọ aṣọ tuntun fún ètò ìsìn ìbí rẹ̀.
1234
1,267
1,269
Ǹjẹ́ Kọ́lá fi ìparun pa irun rẹ?
1234
1,268
1,270
Bọlá ń sọ ìtàn àtẹnudẹ́nu tí òrìṣà mọ́remí lọ́wọ́
1234
1,269
1,271
Ṣe o wà ní ẹka ẹko ní àná?
1234
1,270
1,272
Àwọn tí o bá tan nípa ẹ̀jẹ̀ kò lè fẹ ara wọn.
1234
1,271
1,273
Oni lari ko seda to mola.
1234
1,272
1,274
Òún yóò sọ fún wá ní tí Odùduwa .
1234
1,273
1,275
Ṣé wàá kó àwọn kùkúnbà lọ sí Ọja láti tà?.
1234
1,274
1,276
Àwọn ará Ìlú Ìsẹ́yìn mọ aṣọ hun.
1234
1,275
1,277
Adésọ́lá ṣe giri, ojo nlo.
1234
1,276
1,278
Adé béèrè fún owó Ìrànwọ́ ṣùgbọ́n wọn jà kulẹ̀
1234
1,277
1,279
Orúkọ ẹgbẹ́ mi ni Senuebo.
1234
1,278
1,280
Óunjẹ tí àwọn òṣìṣẹ́ oúnjẹ ilé ìṣe ọkọ̀ Òfurufú fún mi ti kan.
1234
1,279
1,281
Láàbù bàọ́lójì ni mo ti lọ jẹun.
1234
1,280
1,282
Báǹkì máa ń gba owó tí ènìyàn bá gbówó jáde lẹ́ẹ̀mẹta ní báǹkì tí kìí ṣe tẹni
1234
1,281
1,283
Bàbá bàbá rẹ̀ naa fẹ́ ìyàwó mẹ́jọ
1234
1,282
1,284
Ìyẹ̀fun jẹ́ ọ̀kan lára àwọn èròjà pàtàkì láti se puff puff.
1234
1,283
1,285
Mo fẹ́ràn bọ́ọ̀lù alápẹ̀rẹ̀ ju bọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá lọ.
1234
1,284
1,286
Ẹ̀wọ̀n Ìkòyí ni wọ́n rán Bímpẹ́ lọ.
1234
1,285
1,287
Omokunrin naa fun omo mi ni ounje lose to koja
1234
1,286
1,288
Wa pada mi lodo aunti mi lola
1234
1,287
1,289
Ìjàmbá mọ́tọ̀ ṣẹlẹ̀ ní ọ̀nà Àpápá
1234
1,288
1,290
Ṣé irú irun náà nìyí?
1234
1,289
1,291
Mo ló sí etí òkun ní àná
1234
1,290
1,292
Awon okunrin saba maa n lagbara ju obirin lo
1234
1,291
1,293
Ọ̀gá-àgbà 'bìnrin náà jẹ́ olórí ilé ìwé.
1234
1,292
1,294
ilé lan wo ka to somo loruko.
1234
1,293
1,295
Bílèdì dùn fi gẹrun.
1234
1,294
1,296
Yóò forúkọ sílẹ̀ ní ilé-iṣẹ́ ero imohunmaworan
1234
1,295
1,297
Ìgbéyàwó sọ́ọ̀sì ni kí o ṣe!
1234
1,296
1,298
eyinkunle lota wa ile la seni ngbe.
1234
1,297
1,299
Rárá, mi ò ṣe ìpè fídíò pẹ̀lú ọ̀rẹ́ mi.
1234
1,298
1,300
Bàbá náà fẹ dara pọ mó àwọn ológun ní ọdún tó ń bọ̀
1234
1,299
1,301
Mo bu omi sí àwọn ohun ọ̀gbìn náà lánàá.
1234
1,300
1,302
Ṣé arákùnrin náà ṣetán láti yí padà?
1234
1,301
1,303
Olùkọ́ pe àwọn akẹ́kọ̀ọ tó pẹ́ dé
1234
1,302
End of preview. Expand in Data Studio
README.md exists but content is empty.
Downloads last month
41