Dataset Viewer (First 5GB)
Auto-converted to Parquet
audio
audioduration (s)
0.06
22.8
speaker_id
stringlengths
5
5
text
stringlengths
8
191
language
stringclasses
1 value
gender
stringclasses
2 values
age_range
stringclasses
3 values
phase
stringclasses
2 values
MAO41
Ṣé kí n sọ fún ọkọ mi kí ó fi owó náà ránṣẹ́?
yoruba
female
30-over
phase 1
II8KP
Bọ́lá yóò ṣe ọ̀rẹ́-ìyàwọ rẹ.
yoruba
female
18-29
phase 2
Q097Z
Bẹ́́ẹ̀ ni, wọ́n sun òkú Albert einstein níná ni.
yoruba
male
30-over
phase 1
T2EIH
Njẹ awọn igbese yoo wa lati koju awọn ọran ayika ni awọn ghettos iwaju?
yoruba
male
30-over
phase 1
6JOL7
Ń jẹ́ wá lọ sí ọ́fíìsì ni ọ̀la?
yoruba
female
30-over
phase 1
YL7LK
Àjàyí máa gé irun rẹ̀ lọ́la
yoruba
male
18-29
phase 1
YT0T2
Inú Èrọ amúnáwá ńlá ni a ti ń lo epo dísù.
yoruba
male
18-29
phase 2
KJZZS
Àwọn ọmọ tegbọn-taburo máa n f'ọwósowọ́pọ́.
yoruba
female
30-over
phase 1
II8KP
Bolu yóò se ọbẹ̀ àpọ̀n lálẹ́ yìí.
yoruba
female
18-29
phase 2
OYLDH
Ọjọ́rú jẹ́ ìdajì ọ̀sẹ̀
yoruba
male
30-over
phase 1
ELC7E
Wón ti dájò ikú fún Lagata
yoruba
male
30-over
phase 2
NTIVC
Ra àwọn oúnjẹ okun láti ilé itàjà ńlá.
yoruba
female
18-29
phase 1
C974D
Àgbẹ̀ aládàani yóò pọ̀ si ní ọjọ́ iwájú
yoruba
female
6-17
phase 1
JS59W
A máa ń fi ewé sokoyòkòtò ṣe ọbẹ̀ ẹ̀fọ́
yoruba
female
30-over
phase 1
LNXDI
Njé Egufe ní ìyá ma ṣe ní alé yí?
yoruba
female
30-over
phase 1
0CXKQ
Báwo ni iṣu kan ṣe gùn tó?
yoruba
male
30-over
phase 1
V6MKF
O ń bá ọkọ wa sọ̀rọ̀ lọ́wọ́
yoruba
female
18-29
phase 2
HZM4L
O le ri awọn ounjẹ China ni Ikorodu
yoruba
female
30-over
phase 2
59INZ
Tádé sọ̀ pẹ wọn yọọ lọ sí ọjà ni ọla láti gbà awọn ọṣàn díẹ̀ sìí
yoruba
male
18-29
phase 2
Q6KV2
Ì wọlé ìṣẹ́gun ológun padà sínú ìlú ni a máa ń fi k'ààbò pẹ̀lú orin ògo ológun náà
yoruba
female
30-over
phase 2
LNXDI
Ṣé mà á wọ bàtà gíga yìí?
yoruba
female
30-over
phase 1
4MJ2L
Awọn ẹ̀yà alùmíní ṣẹ̀tò awọn iṣẹlẹ, awọn ayé nẹtìwọ̀kì, àti awọn iṣẹ̀ àtílẹ̀yìn fún awọn ọmọ ilẹ̀-ìwé gígá.
yoruba
male
18-29
phase 1
2SCF8
Ọ̀pọ̀ ilé ni kò ní ní pálọ̀ ní ọdún díẹ̀ si.
yoruba
female
18-29
phase 2
O7XY7
Àwọn onígbàjámọ̀ ń lo onírúurú ọ̀nà láti ṣe irun ọkùnrin lóge.
yoruba
male
6-17
phase 1
H45PW
ràrá wón ní fún ní beeli.
yoruba
female
18-29
phase 1
RN4RN
àwọn ọdẹ ní ilé ìtajà kìí ní ìbọn
yoruba
female
30-over
phase 1
0C0M3
So fun ki o yera fún àwon irúfé oúnje kan ti o le sakoba fun omo
yoruba
female
30-over
phase 1
YT0T2
Àìsàn kòrónà tán káàkiri.
yoruba
male
18-29
phase 2
YT0T2
Ṣé ó ṣe lẹ́móléd bréèdì fún ìgbéyàwó ẹ̀?
yoruba
male
18-29
phase 2
7Q08A
Àwọn ìgbẹ̀yìn ìdájọ́ yóò di gbígbé jáde sí orí afẹ́fẹ́ lórii tẹlifísàn
yoruba
female
30-over
phase 1
ZLOOP
Dele yóò wa igi dogoyaro ni ọla
yoruba
male
18-29
phase 2
KSYPO
Mo má gba yàrá méjì ni ọ̀sẹ̀ tó ń bọ̀
yoruba
female
18-29
phase 2
FCX3E
À pàdé ní pàpà ọkọ̀ ayọ̀kẹ̀lé.
yoruba
female
6-17
phase 1
EN10J
Igi agbon le gbe diẹ sii ju ọgọrun-un agbon.
yoruba
female
18-29
phase 1
HZM4L
Bẹ́ẹ̀ni, mo máa lọ sí oko ilé-ìwé náà ní ọ̀la
yoruba
female
18-29
phase 2
OZCG2
Ẹ má jẹ́ kí Idì yẹn fò!
yoruba
female
30-over
phase 2
VAO6L
Awọn itunu yoo wa ni rán nigbamii
yoruba
male
18-29
phase 2
2WJTR
Bẹ́ẹ̀ni, olùrànlọ́wọ́ náà ń ṣètọ́jú àwọn akẹ́kọ̀ọ́ náà
yoruba
female
18-29
phase 2
MGWAM
Wọ́n máa dìbò yan gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́
yoruba
female
18-29
phase 2
Q7FW1
Èmi ni mo gbé kílípà mi lọ sí sọ́ọ̀bù Onigbajamọ̀
yoruba
female
18-29
phase 2
Q7FW1
Mo sọ fún ọ kí o bẹ ìyá rẹ.
yoruba
female
18-29
phase 2
2WJTR
Ọmọ ọwọ́ ò mòtún kò mòsì.
yoruba
female
18-29
phase 2
XUKLM
Oníbàárà mi ṣẹ̀ṣẹ̀ kúrò ni
yoruba
female
18-29
phase 1
YT0T2
Ẹyinjú Bọ́lá Pupa ó dàbí ẹni pé ó ti lóyún.
yoruba
male
18-29
phase 2
1O7ZA
Wọ́n ṣàgbéjáde fọ́nrán kan sí orí YouTube nípa ìrìn àjò wọn.
yoruba
female
18-29
phase 1
HNSNF
Témi ṣẹ̀ṣẹ̀ ṣí ilé ìtura sípà tuntun sí Lẹ́kí ni ìgbà díẹ̀ sẹ́yìn
yoruba
female
18-29
phase 2
MOWN7
Bẹ́ẹ̀ni, Funke ní ìrírí súnmọ́ ara rẹ̀ gidi gan-an nínú ìran rẹ̀.
yoruba
male
30-over
phase 1
OGBX8
wá á wo agbésùmọ̀mí náà!
yoruba
female
30-over
phase 1
SRYA7
Adepoju lè ní àǹfààní lílo ẹ̀rọ tuntun fún àrà irun tó dára jùlọ fún àwọn oníbàárà rẹ̀ ní ọjọ́ iwájú.
yoruba
female
18-29
phase 2
KONPA
Nàíjíríà ni igbó Sambisa wà.
yoruba
female
18-29
phase 1
HNSNF
Eré ìdíje Bọ́ọ̀lù alápẹ̀rẹ̀ yóò wáyé ní ilé ìwé wa ní ọdún tó ń bọ̀
yoruba
female
18-29
phase 2
7TZW9
Fásitì Ìbàdàn ni mo ti kọ́kọ́ gbọ́ orin Barrister Àyìndé.
yoruba
male
18-29
phase 2
BN1ZC
Àwọn kan kò mọ̀ wípé ọ̀nà ìbímọ Sí-Ẹsì kò léwu.
yoruba
female
18-29
phase 2
8I0YX
Amofin náà gbèjà ẹni tó jẹ̀bi ní ilé ẹjọ́
yoruba
male
30-over
phase 1
U1KVJ
Taàní olùdarí ilé iṣẹ́ ìwé títẹ̀ náà?
yoruba
male
30-over
phase 1
2WJTR
Mo sọ pé kí o gba yẹn si mi!
yoruba
female
18-29
phase 2
ZLOOP
Bọ́ọ̀lù aláfẹsẹ̀gbá ni ó gbajúmọ̀ jùlọ.
yoruba
male
18-29
phase 2
43FB0
Béèni, ìyà-àgbà sọ ​​ìtàn kan fun ọ ni alẹ́ àná
yoruba
female
30-over
phase 2
LFWC9
O lè dákú tí o bá jẹ eepo igi dongóyárò
yoruba
male
30-over
phase 1
BYD73
Fọlákẹ́ yá Bólú ní ọ̀kan lára àwọn bírò rẹ̀.
yoruba
female
18-29
phase 1
YT0T2
Ìwà ìrẹ̀lẹ̀ Bọ̀dé jẹ́ kí àwọn ènìyàn fẹ́ràn rẹ̀.
yoruba
male
18-29
phase 2
LA0Y9
Àwùjọ Yorùbá kì í ní kò ní ilé ìwé kankan ní àwùjọ wọn ní ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀
yoruba
female
18-29
phase 2
HUE0L
Adésolá yóò yí ilẹ̀ àyágbé rẹ̀ pada ni ìgba ikàwé tó n bọ́.
yoruba
male
18-29
phase 1
8SJ3J
Folake gbẹ́kẹ̀lé àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ ó sì máa ń pa àṣírí wọn mọ́.
yoruba
female
18-29
phase 1
GCUI4
Ojó ìsẹ́gun to kojá ni odún ògún
yoruba
female
6-17
phase 1
XPYBH
Ǹjẹ́ o fẹ́ràn àwọn àwọn sinimá ẹ̀rù?
yoruba
female
18-29
phase 1
CSMDP
Níbo ni ibi tí adágún odò náà wà?
yoruba
female
18-29
phase 2
9BO6Y
Àgbo àwọ́ká ń ṣiṣẹ́ ju Tábílẹ̀tì àwọ́ká lọ.
yoruba
male
18-29
phase 1
ZHR4X
Mo díbò fún APC
yoruba
female
18-29
phase 2
5OVY6
Jide rà iké ọ̀dá mẹ̀wá làná
yoruba
male
18-29
phase 1
1BW14
Ẹ̀sìn Júdà ń tẹ́lẹ̀ òfin sábáàtì
yoruba
female
30-over
phase 1
W8MQ2
Igi ọsàn tó wà ní iwájú kílásì mi ti so àwọn èso
yoruba
female
30-over
phase 2
P73VN
Ìyá Àdìó ń ta ìgbálẹ̀
yoruba
female
30-over
phase 1
2DBMP
Ọjọ́ kẹta, oṣù Ẹrẹ́nà ni wọ́n bí mi
yoruba
female
30-over
phase 1
LA0Y9
Ọṣẹ ìfọ̀wọ máa ń wà nínú ilé ìgbọ̀nsẹ̀.
yoruba
female
18-29
phase 2
OZCG2
Báwo ni Ọ̀kùn náà ṣe wọlé?
yoruba
female
30-over
phase 2
MGWAM
Wọn á rọ́pò óniṣirò ilé ìfowópamọ́ yẹn, kìí ṣé akọ̀sẹ̀ mọṣẹ́
yoruba
female
18-29
phase 2
7TZW9
Ọgbẹni Usman yọọ rẹrín musẹ sí gbogbo eníyan tí o wa sinu ile-iwe naa.
yoruba
male
18-29
phase 2
QG4N9
Mo ṣe awari awọn akọle ninu itan agbegbe mi.
yoruba
female
18-29
phase 1
HZM4L
O kò ní se àṣà ìlọ́kọ púpọ̀!
yoruba
female
30-over
phase 2
V88AZ
Inú táǹkì epo ni wọ́n rọ epo sí lánàá.
yoruba
male
18-29
phase 1
XKTV1
Prókódi jè ógún kàtá
yoruba
male
30-over
phase 1
DHXFF
Ṣé wà á fi ṣísù yẹn gé igi yìí lọ́la?
yoruba
male
30-over
phase 1
Q7FW1
Mo ràn brọ̀dá mi lówó pẹ̀lú isẹ́ àmúrelé re lánàá.
yoruba
female
18-29
phase 2
43FB0
Bẹ́èni, mo máa ń ṣe ṣùkú lóòrèkóòrè.
yoruba
female
30-over
phase 2
0X1E0
Omi tí a lò nínú ilé ìwè má gba inúu síńkì ilé ìwè jáde
yoruba
male
18-29
phase 1
MO1CL
Ago mẹ́ta ni wọ́n bẹ̀rẹ̀ ìtàn sísọ.
yoruba
male
30-over
phase 1
OZ82A
Ìpínlẹ̀ Niger ni odò Niger wà.
yoruba
male
30-over
phase 1
Z9ZVR
Ìgbà wo ni wà á ṣe irun krọ́ṣẹ́tì fún mi?
yoruba
male
18-29
phase 1
XVPXV
Rárá mi ò jẹ mọ́ńgòrò
yoruba
female
30-over
phase 1
7TZW9
kìnìún ní ara ti o le ti o sí yi
yoruba
male
18-29
phase 2
T84LI
lati dinku irora àyà yago fun awọn ounjẹ ọra ati chocolate
yoruba
male
30-over
phase 1
YQUQL
Ṣé Pẹ́pẹ́yẹ́ ní ìyẹ́?
yoruba
female
18-29
phase 1
ERQYO
A ní adájọ́ méjìléláàádọ́rin ní Nàìjíríà.
yoruba
female
30-over
phase 1
AZ6NE
Lọ gba owó fún mi ní ilé-ifowópamọ gbogbogbò!
yoruba
female
6-17
phase 1
DHGUM
Màá lọ ra òjìlélẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀fà ìwé ní ilé ìtajà-ìwé.
yoruba
female
30-over
phase 1
FE4X8
Àtùnlèse náà máa n gbà yàrá ikẹkọọ láràárọ̀.
yoruba
female
18-29
phase 1
8M4FR
Olùkọ́ máa wá kọ́ wa nílé ní àárọ̀ ọ̀la
yoruba
female
18-29
phase 1
ZHR4X
Màá ra ẹ̀rọ-agbẹ-irun náà fún ẹ nígbà tí Mo ba gba owo oṣù mi
yoruba
female
18-29
phase 2
HXQUJ
Mo mu díẹ̀ nínú oúnjẹ ọmọ náà.
yoruba
male
18-29
phase 1
End of preview. Expand in Data Studio

No dataset card yet

Downloads last month
117